Jẹ́nẹ́sísì 16:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, Ṣáráì wí fún Ábúrámù pé, “Kíyèsí i Olúwa ti sé mi ní inú, èmi kò sì bímọ, wọlé tọ ọmọ ọ̀dọ̀ mi lọ, bóyá èmi yóò le ti ipaṣẹ̀ rẹ̀ ní ọmọ.”Ábúrámù sì gba ohun tí Ṣáráì sọ.

Jẹ́nẹ́sísì 16

Jẹ́nẹ́sísì 16:1-12