Jẹ́nẹ́sísì 16:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣáráì, aya Ábúrámù kò bímọ fún un, ṣùgbọ́n ó ní ọmọ ọ̀dọ̀ obìnrini ará Éjíbítì kan tí ń jẹ́ Ágárì.

Jẹ́nẹ́sísì 16

Jẹ́nẹ́sísì 16:1-6