Jẹ́nẹ́sísì 16:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ágárì sì bí ọmọkùnrin kan fún Ábúrámù, Ábúrámù sì pe orúkọ rẹ̀ ní Ísímáélì.

Jẹ́nẹ́sísì 16

Jẹ́nẹ́sísì 16:5-16