Jẹ́nẹ́sísì 16:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ni a ṣe ń pe kànga náà ní Beeri-Lahai-Róì: kànga ẹni alààyè tí ó rí mi. Ó wà lágbedeméjì Kédásì àti Bérédì.

Jẹ́nẹ́sísì 16

Jẹ́nẹ́sísì 16:5-16