Jẹ́nẹ́sísì 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúrámù sì tún tẹ̀ṣíwájú pé, “Ìwọ kò fún mi ní ọmọ, nítorí náà ẹrú nínú ilé è mi sì ni yóò jẹ́ àrólé mi.”

Jẹ́nẹ́sísì 15

Jẹ́nẹ́sísì 15:1-4