Jẹ́nẹ́sísì 15:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí oòrùn wọ̀ tí ilẹ̀ sì sú, ìkòkò iná tí ń sèéfín àti ọwọ́ iná sì ń kọjá láàrin ẹ̀là a ẹran náà.

Jẹ́nẹ́sísì 15

Jẹ́nẹ́sísì 15:12-21