Jẹ́nẹ́sísì 15:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìran kẹ́rin àwọn ìran rẹ yóò padà wá sí ibi. Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ará Ámórì kò ì tí ì kún òṣùwọ̀n.”

Jẹ́nẹ́sísì 15

Jẹ́nẹ́sísì 15:9-20