Jẹ́nẹ́sísì 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì pe òfúurufú ní “Ọ̀run,” àsálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kejì.

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:1-11