Jẹ́nẹ́sísì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì dá òfuurufú láti ya omi tí ó wà ní òkè òfuurufú kúrò lára omi tí ó wà ní orí ilẹ̀. Ó sì rí bẹ́ẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:1-10