Jákọ́bù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni àwa fi ń yin Olúwa àti Baba, òun ni a sì fi ń bú ènìyàn tí a dá ní àwòrán Ọlọ́run.

Jákọ́bù 3

Jákọ́bù 3:7-12