Jákọ́bù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ẹnu kan náà ni ìyìn àti èébú ti ń jáde. Ẹ̀yin ará mi, nǹkan wọ̀nyí kò yẹ kí ó rí bẹ́ẹ̀.

Jákọ́bù 3

Jákọ́bù 3:6-18