Jákọ́bù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ó gbọ́n tí ó sì ní ìmọ̀ nínú yín? Ẹ jẹ́ kí ó fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nípa ìwà rere, nípa ìwà tútù ti ọgbọ́n.

Jákọ́bù 3

Jákọ́bù 3:10-16