Ẹ̀yin ará mi, igi ọ̀pọ̀tọ́ ha le so èso ólífì bí? Tàbí àjàrà ha lè so èso ọ̀pọ̀tọ́? Bẹ́ẹ̀ ni orísun kan kò le sun omíró àti omi tútù.