Ísíkẹ́lì 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo gbọ́ tó kígbe pé, “Mú àwọn olùṣọ́ ìlú súnmọ́ ìtòsí, kí olúkúlùkù wọn mú ohun ìjà olóró lọ́wọ́.”

Ísíkẹ́lì 9

Ísíkẹ́lì 9:1-9