Ísíkẹ́lì 8:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ń o fi ìbínú bá wọn wí; n kò ní i dá wọn sí bẹ́ẹ̀ ni n kò sì ní fojú àánú wò wọ́n. Bí wọ́n tilẹ̀ ń pariwo sí mi létí, n kò ní fetí sí wọn.”

Ísíkẹ́lì 8

Ísíkẹ́lì 8:12-18