Ísíkẹ́lì 48:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìpín pàtàkì tí ìwọ yóò fifún Olúwa yóò jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (25,000) ní gígùn àti ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́ ni fífẹ̀.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:7-17