Ísíkẹ́lì 48:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí yóò jẹ́ ìpín ibi mímọ́ fún àwọn àlùfáà. Yóò jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́ ni gígùn ní ìhà àríwá, ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́ ni ìhà ìlà oòrùn, ó sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn ní ìhà gúsù. Ní àárin gbùngbùn rẹ̀ ní ilé fún Olúwa yóò wà.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:2-14