Ísíkẹ́lì 48:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Júdà yóò ní ìpín kan; èyí yóò jẹ́ ààlà agbégbé Rúbẹ́nì láti ìlà oòrùn lọ sí ìwọ̀ oòrùn.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:5-8