Ísíkẹ́lì 48:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Níti àwọn ẹ̀yà tí ó kù: Bẹ́ńjámínì yóò ní ìpín kan; Yóò wà láti ìhà ìlà oòrùn títí dé ìhà ìwọ̀ oòrùn.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:16-31