Ilẹ̀ ìní àwọn Léfì àti ohun ìní ìlú ńlá náà yóò wà ni àárin agbégbé tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ aládé. Agbégbé tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ aládé yóò wà ní àárin ààlà tí Júdà àti ààlà tí Bénjámínì.