Ísíkẹ́lì 46:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọrẹ ẹbọ sísun tí ọmọ aládé mú wá fún Olúwa ni ọjọ́ ìsinmí ní láti jẹ́ ọ̀dọ́ àgbò mẹ́fà àti àgbò kan, gbogbo rẹ̀ gbọdọ̀ jẹ́ aláìlábùkù.

Ísíkẹ́lì 46

Ísíkẹ́lì 46:1-12