Ísíkẹ́lì 46:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àwọn ọjọ́ ìsinmi àti àwọn oṣù tuntun ni kí àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà jọ́sìn ní iwájú Olúwa ní àbáwọlé ẹnu ọ̀nà.

Ísíkẹ́lì 46

Ísíkẹ́lì 46:1-8