Ísíkẹ́lì 42:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní iwájú àwọn ọ̀nà, yàrá wà nínú tí ó jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ní fífẹ̀ tí ó sì jẹ́ ọgọ́ọrùn ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn. Àwọn ilẹ̀kùn wọn wà ní apá ìhà àríwá.

Ísíkẹ́lì 42

Ísíkẹ́lì 42:1-6