Ísíkẹ́lì 42:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Méjèèjì ní ogún ìgbọ̀nwọ́ ìpín láti inú ilé ìdájọ́ àti ni ìpín tí ó dojúkọ iwájú ìta ìdájọ́, ọ̀dẹ̀dẹ̀ lókè kọjú sì ọ̀dẹ̀dẹ̀ lókè ní ìdọ́gba mẹ́ta.

Ísíkẹ́lì 42

Ísíkẹ́lì 42:1-7