Ísíkẹ́lì 42:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ọ̀nà ni iwájú wọn rí gẹ́gẹ́ bí ti ìrí àwọn yàrá tí ó wà ní ọ̀nà àríwá bí wọ́n ti gùn mọ bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gbòòrò mọ àti gbogbo ìjáde wọn sì dàbí ìṣe wọn àti bí ìlẹ̀kùn wọn

Ísíkẹ́lì 42

Ísíkẹ́lì 42:5-15