Ísíkẹ́lì 42:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìhà gúsù lọ sí ìbú ògiri ìta ilé ìdájọ́ tí o ṣe déédé pẹ̀lú àgbàlá ilé Ọlọ́run, ní òdìkejì ògiri ìta ni àwọn yàrá náà wà.

Ísíkẹ́lì 42

Ísíkẹ́lì 42:2-15