Ísíkẹ́lì 42:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ó mú mi lọ sí ìta gbangba ni ìhà àríwá ó sì mú mi wọ àwọn yàrá ni òdìkejì ìta gbangba ilé Ọlọ́run àti ni òdìkejì ogiri ìta ní apá ìhà àríwá.

Ísíkẹ́lì 42

Ísíkẹ́lì 42:1-10