Ísíkẹ́lì 41:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ẹ̀gbẹ́ àwọn ògiri ẹnu ọ̀nà ní àwọn fèrèsé tóóró pẹ̀lú igi ọ̀pẹ tí a fín ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì wà. Àwọn yàrá ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ ilé Ọlọ́run náà ni ìbòrí tí a fi igi ṣe.

Ísíkẹ́lì 41

Ísíkẹ́lì 41:21-26