Ísíkẹ́lì 4:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì fi páànù irin kan ṣe ògiri láàrin rẹ̀ àti ìlú yìí, dojú kọ ọ́, kí o sì gbógun tì í. Èyí yóò jẹ́ àmì fún ilé Ísírẹ́lì.

Ísíkẹ́lì 4

Ísíkẹ́lì 4:2-6