Ísíkẹ́lì 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì dó tì í, kí o sì mọ ilé ìṣọ́ tì í, kí o sì mọ odi tì í, kí o sì gbé ogun sí i, kí o sì to òòlù yí i ká.

Ísíkẹ́lì 4

Ísíkẹ́lì 4:1-6