Ísíkẹ́lì 38:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Páṣíà, Kúsì àti Pútì yóò wà pẹ̀lú wọn, gbogbo wọn yóò wà pẹ̀lú asà àti ìsíborí wọn

Ísíkẹ́lì 38

Ísíkẹ́lì 38:1-7