Ísíkẹ́lì 37:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ṣọtẹ́lẹ̀, kí o sì ṣọ fun wọn pé, ‘Èyí yìí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun sọ: Ẹ̀yin ènìyàn mi, Èmi yóò sí àwọn ibojì yín, èmi yóò sì mú yín wá si ilẹ̀ Isírẹ́lì.

Ísíkẹ́lì 37

Ísíkẹ́lì 37:10-13