Ísíkẹ́lì 34:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àgùntàn mi n rin ìrìn àrè kiri ní gbogbo àwọn òkè gíga àti òkè kékeré. A fọ́n wọn ká gbogbo orí ilẹ̀ ẹni kankan kò sì wá wọn.

Ísíkẹ́lì 34

Ísíkẹ́lì 34:1-11