Ísíkẹ́lì 34:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà wọn fọ́n káàkiri nítorí àìsí olùsọ́ àgùntàn, nígbà tí wọ́n fọ́n ká tán wọn di ìjẹ fún gbogbo ẹranko búburú.

Ísíkẹ́lì 34

Ísíkẹ́lì 34:1-11