Ísíkẹ́lì 33:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ènìyàn búburú bá yípadà kúrò nínú búburú rẹ̀, tí ó sì ṣe èyí tí ó tọ́ àti èyí tí ó yẹ, òun yóò yè nípa ṣíṣe bẹ́ẹ̀.

Ísíkẹ́lì 33

Ísíkẹ́lì 33:18-27