Ísíkẹ́lì 29:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ọjọ́ náà, èmi yóò mú kí ilé Ísírẹ́lì ní agbára, èmi yóò sì fún ọ ní ẹnu ọ̀rọ̀ ní àárin wọn. Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa.”

Ísíkẹ́lì 29

Ísíkẹ́lì 29:11-21