Ísíkẹ́lì 29:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ti fi Éjíbítì fún un gẹ́gẹ́ bí èrè wàhálà rẹ̀ nítorí òun àti àwọn ológun rẹ ṣe é fún mi, ni Olúwa Ọlọ́run wí.

Ísíkẹ́lì 29

Ísíkẹ́lì 29:16-21