Ísíkẹ́lì 28:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn rẹ gbéraganítorí ẹwà rẹ.Ìwọ sì ba ọgbọ́n rẹ jẹ́nítorí dídára rẹ.Nítorí náà mo le ọ sórí ayé;mo sọ ọ di awò ojú níwájú àwọn ọba.

Ísíkẹ́lì 28

Ísíkẹ́lì 28:10-23