Ísíkẹ́lì 28:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìtànkálẹ̀ òwò rẹìwọ kún fún ìwà ipá;ìwọ sì dẹ́sẹ̀Nítorí náà ni mo ṣe sọ ọ nùbí ohun àìlọ́wọ̀ kúrò lórí òkè Ọlọ́run.Èmi sì pa ọ run,ìwọ kérúbù, tí ó bọ́ kúrò ní àárin òkúta amúbínà

Ísíkẹ́lì 28

Ísíkẹ́lì 28:12-18