Ísíkẹ́lì 27:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún Tírè, tí a tẹ̀dó sí ẹnu bodè òkun, oníṣòwò àwọn orílẹ̀-èdè fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù. ‘Èyí yìí ní Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Ìwọ Tírè wí pé“Ẹwá mi pé.”

Ísíkẹ́lì 27

Ísíkẹ́lì 27:1-4