Ísíkẹ́lì 27:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọ̀rọ̀ Olúwa tún tọ̀ mí wá wí pé:

2. “Ọmọ ènìyàn, pohùnréré ẹkún fún Tírè.

3. Sọ fún Tírè, tí a tẹ̀dó sí ẹnu bodè òkun, oníṣòwò àwọn orílẹ̀-èdè fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù. ‘Èyí yìí ní Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Ìwọ Tírè wí pé“Ẹwá mi pé.”

4. Ààlà rẹ wà ní àárin òkun;àwọn ọ̀mọ̀lé rẹ ti mú ẹwà rẹ pé.

Ísíkẹ́lì 27