Ísíkẹ́lì 27:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Áránì àti Kánnà àti Édénì, àwọn onísòwò Ṣébà, Ásúrù àti Kílímádì, ni àwọn oníṣòwò rẹ.

Ísíkẹ́lì 27

Ísíkẹ́lì 27:19-30