Ísíkẹ́lì 27:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Àwọn ènìyàn Ródísì ni àwọn oníṣòwò rẹ, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù ni wọ́n jẹ́ onibárà rẹ̀; wọ́n mú eyín-erin àti igi ébónì san owó rẹ.

Ísíkẹ́lì 27

Ísíkẹ́lì 27:14-21