Ísíkẹ́lì 26:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì jẹ́ ibi nína àwọ̀n tí wọn fi ń pẹja sí láàárin òkun, ní Olúwa Ọlọ́run wí. Yóò di ìkógun fún àwọn orílẹ̀ èdè.

Ísíkẹ́lì 26

Ísíkẹ́lì 26:1-6