Ísíkẹ́lì 16:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni mo ṣe ọ́ lọ́ṣọ̀ọ́ pẹ̀lú wúrà àti fàdákà; tí aṣọ rẹ jẹ́ funfun lẹlẹ, olówó iyebíye àti aṣọ tí a ṣiṣẹ́ ọnà sí. Ìyẹ̀fun kíkúnná, oyin àti òróró ni oúnjẹ rẹ. O di arẹwà títí o fi dé ipò ayaba.

Ísíkẹ́lì 16

Ísíkẹ́lì 16:5-20