Ísíkẹ́lì 16:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì tún fi òrùka sí ọ nímú, mo fi yẹtí sí ọ létí, mo sì fi adé tó rẹwà dé ọ lórí.

Ísíkẹ́lì 16

Ísíkẹ́lì 16:11-14