Ísíkẹ́lì 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

N ó lé yín jáde kúrò ní ìlú yìí, n ó sì fà yín lé àlejò lọ́wọ́, n ó sì mú ìdájọ́ ṣẹ lé yín lórí.

Ísíkẹ́lì 11

Ísíkẹ́lì 11:6-17