Ísíkẹ́lì 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa idà ni ẹ ó ṣubú, n ó sì ṣe ìdájọ́ yín ní àwọn ààlà ìlú Ísírẹ́lì. Nígbà náà lẹ ó mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.

Ísíkẹ́lì 11

Ísíkẹ́lì 11:4-11