Ìfihàn 18:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nínú rẹ̀ ní a gbé ri ẹ̀jẹ̀ àwọn wòlíì,àti ti àwọn ènìyàn mímọ́, àti ti gbogbo àwọn tí a pa lórí ilẹ̀ ayé.”

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:16-24