Ìfihàn 18:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ìmọ́lẹ̀ fìtílà ni kì yóò sì tàn nínú rẹ̀ mọ́ láé;a kì yóò sì gbọ́ ohùn ọkọ ìyàwó àti ti ìyàwó nínú rẹ mọ́ láé:nítorí pé àwọn oníṣòwò rẹ̀ ni àwọn ẹni ńlá ayé;nítorí pé nípa ọ̀ṣọ́ rẹ̀ ní a fi tàn orílẹ̀ èdè gbogbo jẹ.

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:16-24